Jẹ́nẹ́sísì 29:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wàyí o, Lábánì ní ọmọbìnrin méjì, orúkọ èyí ẹgbọ́n ń jẹ́ Líà, orúkọ àbúrò sì ń jẹ́ Rákélì.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:13-23