Jẹ́nẹ́sísì 29:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábánì sì wí pé, “Ẹran ara àti ẹ̀jẹ̀ ara mi ni ìwọ jẹ́.”Lẹ́yìn tí Jákọ́bù sì wà pẹ̀lú rẹ̀ fún odidi oṣù kan,

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:10-22