Jẹ́nẹ́sísì 29:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì tẹ̀ṣíwájú nínú ìrìn-àjò rẹ̀, ó sì dé ilẹ̀ àwọn ará ìlà oòrùn.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:1-6