Jẹ́nẹ́sísì 28:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkúta yìí tí mo gbé kalẹ̀ bí ọ̀wọ̀n yóò jẹ́ ilé Ọlọ́run, gbogbo ohun tí O bá sì fún mi, èmi yóò fún Ọ ní ìdámẹ́wàá rẹ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 28

Jẹ́nẹ́sísì 28:19-22