Jẹ́nẹ́sísì 29:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rí kànga kan ní pápá, agbo àgùntàn mẹ́ta sì dúró láti mu omi ní ibi kànga náà, nítorí pé láti-inú kànga náà ni wọ́n ti ń fi omi fún agbo àgùntàn. Òkúta tí a gbé dí ẹnu kànga náà sì tóbi gidigidi.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:1-5