Jẹ́nẹ́sísì 27:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, mú ohun èlò ọdẹ rẹ—apó àti ọrún—nísinsin yìí kí o sì lọ pa ẹran wá fún mi nínú igbó.

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:1-4