Jẹ́nẹ́sísì 27:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísáákì sì wí pé, “Nísinsin yìí mo di arúgbó, èmi kò sì mọ ọjọ́ tí èmi yóò kú.

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:1-4