Jẹ́nẹ́sísì 27:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì ṣe ẹran àdídùn fún mi, irú èyí tí mo fẹ́ràn kí o gbe wá fún mi kí n jẹ, kí n sì súre fún ọ kí n tó kú.”

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:1-9