Jẹ́nẹ́sísì 26:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà gan-an ni àwọn ìránṣẹ́ Ísáákì wá sọ fún un pé àwọn ti kan omi ní kànga kan tí àwọn gbẹ́.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:30-35