Jẹ́nẹ́sísì 26:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì wọn búra fún ara wọn. Ísáákì sì rán wọn lọ, wọ́n sì lọ ní àlàáfíà.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:23-35