Jẹ́nẹ́sísì 26:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì pe orúkọ kànga náà ní Ṣébà (kànga májẹ̀mu), títí di òní olónìí, orúkọ ìlú náà ni Bíáṣébà.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:25-35