Jẹ́nẹ́sísì 26:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà àwọn ará Fílístínì ru erùpẹ̀ di gbogbo kànga tí àwọn ìránṣẹ́ Ábúráhámù baba rẹ̀ ti gbẹ́.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:8-23