Jẹ́nẹ́sísì 26:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Ábímélékì wí fún Ísáákì pé, “Jáde kúrò ní ilẹ̀ wa, nítorí tí ìwọ ti di alágbára púpọ̀ jù wá lọ.”

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:10-26