Jẹ́nẹ́sísì 26:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ní ọ̀pọ̀lopọ̀ ẹran ọ̀sìn àti agbo ẹran àti àwọn ìránṣẹ́ tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn Fílístínì ń ṣe ìlara rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:5-16