Jẹ́nẹ́sísì 26:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì di ọlọ́rọ̀, ọrọ̀ rẹ̀ sì ń pọ̀ si, títí ó fi di ọlọ́rọ̀ gidigidi.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:12-16