Jẹ́nẹ́sísì 24:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ nísin yìí bí ẹ̀yin yóò bá fi inú rere àti òtítọ́ bá olúwa mi lò, ẹ sọ fún mi, bí bẹ́ẹ̀ sì kọ́, ẹ sọ fún mi, kí ó le è mọ ọ̀nà tí èmi yóò yà sí.”

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:45-51