Jẹ́nẹ́sísì 24:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábánì àti Bétúélì sì dáhùn pé, “Lọ́dọ̀ Olúwa ni èyi ti wá, nítorí náà àwa kò le sọ rere tàbí búburú fún ọ.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:49-55