Jẹ́nẹ́sísì 24:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wólẹ̀ mo sì sin Olúwa, Ọlọ́run Ábúráhámù olúwa à mi, ẹni tí ó ṣe amọ̀nà mi láti rí ọmọ ọmọ arákùnrin olúwa mi, mú wá fún ọmọ rẹ̀ (Ísáákì).

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:44-53