Jẹ́nẹ́sísì 21:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì gbin igi Támárísíkì kan sí Báá-Ṣébà, níbẹ̀ ni ó sì pe orúkọ Olúwa Ọlọ́run ayérayé.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:27-34