Jẹ́nẹ́sísì 21:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn májẹ̀mú tí wọ́n dá ní Báá-Ṣébà yìí ni Ábímélékì àti Píkólì olórí ogun rẹ̀ pada sí ilẹ̀ àwọn ará Fílístínì.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:29-33