Jẹ́nẹ́sísì 21:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó ń gbé ni ihà ní Páránì, ìyá rẹ̀ fẹ́ ìyàwó fún un láti ilẹ̀ Éjíbítì wá.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:16-29