Jẹ́nẹ́sísì 21:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì wà pẹ̀lú ọmọ náà bí ó ti ń dàgbà, ó ń gbé nínú ìjù, ó sì di tafàtafà.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:18-23