Jẹ́nẹ́sísì 21:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì ṣí ojú Ágárì, ó sì rí kànga kan, ó lọ ṣíbẹ̀, ó rọ omi kún inú ìgò náà, ó sì fún ọmọ náà mu.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:15-22