Jẹ́nẹ́sísì 20:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ọlọ́run tọ Ábímélékì wá ní ojú àlá lọ́jọ́ kan, ó sì wí fún un pé, “Kíyèsi, kò sí ohun tí o fi sàn ju òkú lọ, nítorí obìnrin tí ìwọ mú sọ́dọ̀, aya aláya ni.”

Jẹ́nẹ́sísì 20

Jẹ́nẹ́sísì 20:1-11