Ábúráhámù sì sọ ní ti Ṣárà aya rẹ̀ níbẹ̀ pé, “Arábìnrin mi ni.” Ábímélékì ọba Gérárì sì ránṣẹ́ mú Ṣárà wá sí ààfin rẹ̀.