Jẹ́nẹ́sísì 20:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ábímélékì kò tí ì bá obìnrin náà lò pọ̀, nítorí náà ó wí pé, “Olúwa ìwọ yóò run orílẹ̀ èdè aláìlẹ́bi bí?

Jẹ́nẹ́sísì 20

Jẹ́nẹ́sísì 20:1-7