Jẹ́nẹ́sísì 20:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì kó kúrò níbẹ̀ lọ sí ìhà gúsù ó sì ń gbé ní agbede-méjì Kádésì àti Ṣúrì; ó sì gbé ní ìlú Gérárì fún ìgbà díẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 20

Jẹ́nẹ́sísì 20:1-6