Jẹ́nẹ́sísì 19:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí àbúrò náà sì bí ọmọkùnrin, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bẹni-Ámì. Òun ni baba ńlá àwọn ará Ámónì lónìí.

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:29-38