Jẹ́nẹ́sísì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà sì wí pé,“Èyí ni egungun láti inú egungun miàti ẹran-ara nínú ẹran-ara mi;‘obìnrin’ ni a ó máa pè énítorí a mú un jáde láti ara ọkùnrin.”

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:13-25