Jẹ́nẹ́sísì 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run sì dá obìnrin láti inú egungun tí ó yọ ní ìhà ọkùnrin náà, ó sì mu obìnrin náà tọ̀ ọ́ wá.

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:19-25