Jẹ́nẹ́sísì 2:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìdí èyí, ọkùnrin yóò fi baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóò sì dàpọ̀ mọ́ aya rẹ̀, wọn yóò sì di ara kan.

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:17-25