Jẹ́nẹ́sísì 19:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ẹ̀gbọ́n sì bí ọmọkùnrin, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Móábù. Òun ni baba ńlá àwọn ará Móábù lónìí.

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:32-38