Jẹ́nẹ́sísì 16:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì náà sì wí fún un pé,“Ìwọ ti lóyún ìwọ yóò sì bíọmọkùnrin kan,ìwọ yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Íṣímáélì,nítorí tí Olúwa ti rí ìpọ́njú rẹ.

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:3-12