Jẹ́nẹ́sísì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò jẹ́ ẹhànnà ènìyànyóò máa tako gbogbo ènìyàn,gbogbo ènìyàn yóò sì máa takò ó,kì yóò sì bá awọn arákùnrin rẹ̀gbé ní ìrẹ́pọ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:7-16