Jẹ́nẹ́sísì 16:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì náà sì fi kún fún un pé, “Èmi yóò sọ ọ́ di orílẹ̀ èdè ńlá, ìran rẹ kì yóò sì lóǹkà.”

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:6-16