Jẹ́nẹ́sísì 15:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹyẹ igún sì ń wá sórí òkú ẹran náà, Ábúrámù sì ń lé wọn.

Jẹ́nẹ́sísì 15

Jẹ́nẹ́sísì 15:8-15