Jẹ́nẹ́sísì 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúrámù sì mú gbogbo nǹkan wọ̀nyí wá, ó sì là wọ́n sí méjìméjì, ó sì fi ẹ̀là èkínní kọjú sí èkejì, ṣugbọ́n kò la àwọn ẹyẹ ní tiwọn.

Jẹ́nẹ́sísì 15

Jẹ́nẹ́sísì 15:9-17