Jẹ́nẹ́sísì 15:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí oòrùn ti ń wọ̀, Ábúrámù sùn lọ fọnfọn, òkùnkùn biribiri tí ó kún fún ẹ̀rù sì bò ó.

Jẹ́nẹ́sísì 15

Jẹ́nẹ́sísì 15:5-14