Jẹ́nẹ́sísì 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọba mẹ́rẹ̀ẹ̀rin náà sì kó gbogbo ẹrù Ṣódómù àti Gòmórà àti oúnjẹ wọn; wọ́n sì lọ.

Jẹ́nẹ́sísì 14

Jẹ́nẹ́sísì 14:1-21