Jẹ́nẹ́sísì 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì mú Lọ́tì ọmọ arákùnrin Ábúrámù tí ń gbé ní Ṣódómù àti gbogbo ohun-ìní rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 14

Jẹ́nẹ́sísì 14:10-16