Jẹ́nẹ́sísì 11:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áránì sì kú ṣáájú Tẹ́rà baba rẹ̀ ní ilẹ̀ ìbí rẹ̀ ní Úrì ti ilẹ̀ Kálídéà.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:25-32