Jẹ́nẹ́sísì 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni ìran Tẹ́rà: Tẹ́rà ni baba Ábúrámù, Náhórì àti Áránì, Áránì sì bí Lọ́tì.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:25-28