Jẹ́nẹ́sísì 11:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúrámù àti Náhórì sì gbéyàwó. Orúkọ aya Ábúrámù ni Sáráì, nígbà tí aya Náhórì ń jẹ́ Mílíkà, tí ṣe ọmọ Áránì. Áránì ni ó bí Mílíkà àti Ísíkà.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:23-31