Jẹ́nẹ́sísì 1:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì rí àwọn ohun gbogbo tí ó dá, ó dára gidigidi. Àsálẹ́ àti òwúrọ̀, ó jẹ́ ọjọ́ kẹfà.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:21-31