Jẹ́nẹ́sísì 1:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti fún àwọn ẹranko inú igbó àti ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ohun afàyàfà: gbogbo ohun tó ní èémí ìyè nínú ni mo fi ewéko fún bí oúnjẹ.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:21-31