Jẹ́nẹ́sísì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Ọlọ́run parí dídá àwọn ọ̀run àti ayé pẹ̀lú ohun gbogbo tí ó wà nínú rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:1-8