Ísíkẹ́lì 48:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mánásè yóò ní ìpín; èyí yóò jẹ́ ààlà ti agbégbé Náfátalì láti ìlà oòrùn sí ìwọ̀ oòrùn.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:3-11