Ísíkẹ́lì 48:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Náfítalì yóò ní ìpín kan; èyí yóò jẹ́ ààlà agbégbé Ásárì láti ìlà oòrùn lọ sí ìwọ̀ oòrùn.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:1-5