Ísíkẹ́lì 48:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Éfúráímù yóò ní ìpín kan; èyí yóò jẹ́ ààlà agbégbé Mánásè láti ìlà oòrùn lọ sí ìwọ oòrùn.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:2-14