Ísíkẹ́lì 37:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọwọ́ Olúwa wà lára mi, ó sì mú mi jáde pẹ̀lú ẹ̀mí Olúwa, ó mú kí ń wà ní àárin àfonífojì; ti o kún fún àwọn egungun.

2. Ó mú mi lọ síwájú àti sẹ́yìn láàrin wọn, èmi sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn egungun ní orí ilẹ̀ àfonífojì, àwọn egungun tí ó gbẹ gan.

Ísíkẹ́lì 37